Jóṣúà 9:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsinyí, àwa wà ní ọwọ́ yín. Ohunkóhun tí ẹ bá rò pé ó yẹ ó si tọ́ lójú yín ní kí ẹ fi wá ṣe.”

Jóṣúà 9

Jóṣúà 9:16-27