Jóṣúà 9:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ẹ̀yìn ọjọ́ mẹ́ta tí wọ́n ti ṣe àdéhùn pẹ̀lú àwọn ará Gíbíónì, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbọ́ pé aládùúgbò wọn ni wọ́n, tí ń gbé ní tòsí wọn.

Jóṣúà 9

Jóṣúà 9:6-19