Jóṣúà 9:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ìgò wáìnì wọ̀nyí, tí àwa rọ kún tuntun ni, ṣùgbọ́n ẹ wò ó bí wọ́n ti sán. Asọ àti bàtà wa ni ó sì ti gbó nítorí ìrìnàjò ọ̀nà jínjìn.”

Jóṣúà 9

Jóṣúà 9:11-19