Jóṣúà 8:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn èyí, Jóṣúà sì ka gbogbo ọ̀rọ̀ inú òfin ìbùkún àti ègún-gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ nínú Ìwé Òfin.

Jóṣúà 8

Jóṣúà 8:29-35