Jóṣúà 8:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹgbẹ̀rún méjìlá ọkùnrin àti obìnrin ni ó kú ní ọjọ́ náà-gbogbo wọn jẹ́ àwọn ènìyàn Áì.

Jóṣúà 8

Jóṣúà 8:19-30