Jóṣúà 8:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì pe gbogbo àwọn ọkùnrin Áì jọ láti lépa wọn, wọ́n sì lépa Jóṣúa títí wọ́n fi tàn wọ́n jáde nínú ìlú náà.

Jóṣúà 8

Jóṣúà 8:8-21