Jóṣúà 7:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósúà sì fa aṣọ rẹ̀ ya, ó sì dojú bolẹ̀ níwájú àpótí ẹ̀rí Olúwa títí di àṣálẹ́. Àwọn àgbà Ísírẹ́lì sì ṣe bákan náà, wọ́n ku eruku sí orí i wọn.

Jóṣúà 7

Jóṣúà 7:1-9