Jóṣúà 7:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Jóṣúà ran àwọn òjíṣẹ́, wọ́n sì ṣáré wọ inú àgọ́ náà, ó sì wà níbẹ̀, a sì fi pamọ́ nínú àgọ́ ọ rẹ̀, àti fàdákà ní abẹ́ ẹ rẹ̀.

Jóṣúà 7

Jóṣúà 7:20-24