Jóṣúà 7:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ọjọ́ kéjì, Jóṣúà mú Ísírẹ́lì wá ṣíwájú ní ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan, a sì mú ẹ̀yà Júdà.

Jóṣúà 7

Jóṣúà 7:13-26