Jóṣúà 4:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí Olúwa Ọlọ́run yín mú Jọ́dánì gbẹ ní iwájú u yín títí ẹ̀yin fi kọjá. Olúwa Ọlọ́run yín ti ṣe sí Jọ́dánì gẹ́gẹ́ bí ó ti se sí Òkun Pupa, nígbà tí ó mú un gbẹ ní iwájú wa títí àwa fi kọjá.

Jóṣúà 4

Jóṣúà 4:17-24