Jóṣúà 3:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Odò Jọ́dánì sì máa ń wà ní kíkún ní gbogbo ìgbà ìkórè. Ṣùgbọ́n bí àwọn àlùfáà tí ó ru àpótí ẹ̀rí ti dé odò Jọ́dánì, tí ẹṣẹ̀ wọn sì kan etí omi,

Jóṣúà 3

Jóṣúà 3:14-17