Jóṣúà 24:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì sin ín sí ilẹ̀ ìní rẹ̀, ní Tíminátì Sérà ni ilẹ̀ orí òkè Éfúráímù, ní ìhà àríwá Òkè Gááṣì.

Jóṣúà 24

Jóṣúà 24:26-33