Jóṣúà 24:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì rán oyin sí iwájú yín, tí ó lé wọn kúrò ní iwájú yín, àní ọbá Ámórì méjì. Ẹ kò ṣe èyí pẹ̀lú idà yín àti ọrun yín.

Jóṣúà 24

Jóṣúà 24:6-15