Jóṣúà 23:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì pe gbogbo Ísírẹ́lì jọ: àgbààgbà wọn, olórí wọn, adájọ́ àti àwọn ìjòyè, ó sì sọ fún wọn pé, “Èmi ti pọ̀ ní ọdún èmi ti di arúgbó.

Jóṣúà 23

Jóṣúà 23:1-10