Jóṣúà 22:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kò fi àwọn arákùnrin yín sílẹ̀ láti ìgbà yí títí di òní, ṣùgbọ́n ẹ ti kíyèsára láti pa òfin Olúwa Ọlọ́run yín mọ́.

Jóṣúà 22

Jóṣúà 22:1-4