Jóṣúà 21:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ẹ̀yà Gásónì ni a pín ìlú mẹ́talá fún láti ara ẹ̀yà Ísákárì, Áṣíérì, Náfitalì àti ìdajì ẹ̀yà Mánásè ní Básánì.

Jóṣúà 21

Jóṣúà 21:5-11