Jóṣúà 21:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ara ẹ̀yà Gádì ní wọ́n ti fún wọn níRámótìa ní Gílíádì (tí ó jẹ́ ìlú ààbò fún apànìyàn), Máhánáímù,

Jóṣúà 21

Jóṣúà 21:31-44