Jóṣúà 21:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní Sílò, ní Kénánì, wọn sọ fún wọn pé, “Olúwa pàṣẹ nípasẹ̀ Mósè pé kí wọn fún wa ní ìlú láti máa gbé àti ilẹ̀ pápá oko tútù fún ẹran ọ̀sìn wa.”

Jóṣúà 21

Jóṣúà 21:1-7