Jóṣúà 21:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àfikún wọ́n sì fún àwọn ọmọ Árónì tí í ṣe àlùfáà ní Hébúrónì (ọ̀kannínú ìlú ààbò fún àwọn apàníyàn) pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko tútù rẹ̀, Líbínà,

Jóṣúà 21

Jóṣúà 21:3-19