Jóṣúà 20:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọn yan àwọn ìlú ààbò, gẹ́gẹ́ bí mo ti pàṣẹ fún ọ láti ẹnu Mósè,

Jóṣúà 20

Jóṣúà 20:1-9