Jóṣúà 2:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì sọ fún Jóṣúà, “Nítòótọ́ ni Olúwa tí fi gbogbo ilẹ̀ náà lé wa lọ́wọ́; gbogbo olùgbé ilẹ̀ náà ni ìbẹ̀rù-bojo ti mú nítorí i wa.”

Jóṣúà 2

Jóṣúà 2:16-24