Jóṣúà 2:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dáhùn pé, “Ó dára bẹ́ẹ̀.” “Ẹ jẹ́ kí ó rí gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin tí ṣọ.” Ó sì rán wọn lọ, wọ́n sì lọ. Ó sì so okùn òdòdó náà sí ojú u-fèrèsé.

Jóṣúà 2

Jóṣúà 2:19-24