Jóṣúà 19:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Írónì, Mígídálì-Élì, Hórémù, Bẹ́tì-Ánátì àti Bẹ́tì-Sẹ́mẹ́ṣì. Wọ́n sì jẹ́ ìlú mọ́kàndínlógún àti ìletò wọn.

Jóṣúà 19

Jóṣúà 19:37-39