Jóṣúà 19:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ààlà náà sì tẹ̀ sí ìhà Rámà, ó sì lọ sí ìlú olódi Tirè, ó sì yà sí Hósà, ó sì jáde ní òkun ní ilẹ̀ Ákísíbì,

Jóṣúà 19

Jóṣúà 19:26-32