Jóṣúà 19:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lára wọn ni Kátatì, Náhalálì, Símírónì, Ìdálà àti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù. Wọ́n sì jẹ́ ìlú méjìlá àti ìletò wọn.

Jóṣúà 19

Jóṣúà 19:7-25