Jóṣúà 19:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì yípadà sí ìlà-oòrùn láti Sérídì sí ìhà ìlà-oòrùn dé ilẹ̀ Kisiloti-Tábórì, ó sì lọ sí Dábérátì, ó sì gòkè lọ sí Jáfíà.

Jóṣúà 19

Jóṣúà 19:4-16