Jóṣúà 19:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Gègé kéjì jáde fún ẹ̀yà Símíónì, ní agbo ilé, ní agbo ilé. Ìní wọn sì wà ní àárin ilẹ̀ Júdà.

2. Lára ìpín wọn ní:Béérí Ṣébà (tàbí Ṣẹ́bà), Móládà,

3. Hasari-Ṣúálì, Báláhì, Ésémù,

4. Élítóládì, Bétúlì, Hómà,

Jóṣúà 19