Jóṣúà 18:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Odò Jọ́dánì sí jẹ́ ààlà ní ìhà ìlà-oòrùn.Ìwọ̀nyí ní àwọn ààlà ti ó ṣàmì sí ìní àwọn ìdílé Bẹ́ńjámínì ní gbogbo àwọn àyíká wọn.

Jóṣúà 18

Jóṣúà 18:16-25