Jóṣúà 17:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ààlà náà sì tún tẹ̀ṣíwájú lọ sí gúsù dé Kana-Ráfínì. Àwọn ìlú tí ó jẹ́ ti Éfúráímù wà ní àárin àwọn ìlú Mánásè, ṣùgbọ́n ààlà Mánásè ni ìhà àríwá Ráfínì, ó sì pin sí òkun.

Jóṣúà 17

Jóṣúà 17:6-18