Jóṣúà 17:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí àwọn ọmọbìnrin ẹ̀yà Mànásè gba ìní ní àárin àwọn ọmọkùnrin. Ilẹ̀ Gílíádì sì jẹ́ ti ìyókù àwọn ọmọ Mánásè.

Jóṣúà 17

Jóṣúà 17:1-7