Jóṣúà 17:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìn yìí Sẹloféádì ọmọ Héférì, ọmọ Gílíádì, ọmọ Mákírì, ọmọ Mánásè, kò ní ọmọkùnrin, bí kò se àwọn ọmọbìnrin, tí orúkọ wọn jẹ́: Málà, Nóà, Hógílà, Mílíkà àti Tásà.

Jóṣúà 17

Jóṣúà 17:1-13