Jóṣúà 17:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣíbẹ̀, àwọn ọmọ Mánásè kò lè gba àwọn ìlú wọ̀nyí, nítorí àwọn ará Kénánì ti pinnu láti gbé ní ilẹ̀ náà.

Jóṣúà 17

Jóṣúà 17:8-18