Jóṣúà 16:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti Tápúà ààlà náà sì lọ sí ìhà ìwọ̀-oòrùn, ní Kana-Ráfínì, ó sì parí ní òkun. Èyí ni ìní ẹ̀yà àwọn ọmọ Éfúráímù, ní agbo ilé agbo ilé.

Jóṣúà 16

Jóṣúà 16:6-9