Jóṣúà 15:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ààlà náà sì tún gòkè lọ sí Àfonífojì Bẹni Hínómù ní ìhà gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ gúsù ti Jébúsì (tí í ṣe Jérúsálẹ́mù). Ó sì gòkè lọ sí orí òkè tí ó wà lórí Àfonífojì Hínómù ní òpín àríwá àfonífojì Réfáímù.

Jóṣúà 15

Jóṣúà 15:3-9