Jóṣúà 15:63 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Júdà kò lè lé àwọn ọmọ Jébúsì jáde, tí wọ́n ń gbé ní Jérúsálẹ́mù. Àwọn ará Jébúsì sì ń gbé pẹ̀lú àwọn ènìyàn Júdà títí dí òní.

Jóṣúà 15

Jóṣúà 15:58-63