Jóṣúà 15:39-44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

39. Lákísì, Bósíkátì, Égílónì,

40. Kábónì, Lámásì, Kítílísì,

41. Gédérótì, Bẹti-Dágónì, Náámà àti Mákédà, ìlú mẹ́rìndín ní ogún àti ìletò wọn.

42. Líbínà, Étíérì, Áṣánì,

43. Hífítà, Ásínà, Nésíbù,

44. Kéílà, Ákísíbì àti Máréṣà, ìlú mẹ́sàn àti àwọn ìletò wọn. (9)

Jóṣúà 15