Jóṣúà 15:29-35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

29. Báálà, Hímù, Ésémù,

30. Elitóládì, a Késílì, Hórímà,

31. Síkílágì, Mádímánà, Sánsánà,

32. Lébáótì, Sílímù, Háínì àti Rímónì, àpapọ̀ ìlú mọ́kàndín ní ọgbọ̀n àti àwọn ìlétò wọn.

33. Ní ìhà ìwọ̀-oòrùn ẹsẹ̀ òkè:Ésítaólì, Sórà, Áṣínà,

34. Sánóà, Eni-Gánímù, Tápúà, Énámù,

35. Jámútì, Ádúlámù, Sókò, Ásekà,

Jóṣúà 15