Jóṣúà 14:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ náà, Mósè búra fún mi pé, ‘Ilẹ̀ tí ẹsẹ̀ rẹ ti rìn ni yóò jẹ́ ìní rẹ àti ti àwọn ọmọ rẹ láéláé, nítorí pé ìwọ fi tọkàntọkàn wà Pẹ̀lú Olúwa Ọlọ́run mi.’

Jóṣúà 14

Jóṣúà 14:8-13