Jóṣúà 14:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo jẹ́ ọmọ ogójì ọdún nígbà tí Mósè ìránṣẹ́ Olúwa rán mi láti Kádesi-Báníyà lọ rin ilẹ̀ náà wò. Mo sì mú ìròyìn wá fún un gẹ́gẹ́ bí o ti dá mi lójú,

Jóṣúà 14

Jóṣúà 14:6-13