Jóṣúà 14:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè ti fún àwọn ẹ̀yà méjì àti ààbọ̀ ní ogún wọn ní ìlà-oòrùn Jọ́dánì, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ Léfì ni kò fi ìní fún ní àárin àwọn tí ó kù.

Jóṣúà 14

Jóṣúà 14:1-11