Jóṣúà 14:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Joṣua súre fun Kélẹ́bù ọmọ Jéfún ó si fun un ní Hébúrónì ni ilẹ̀ ìni

Jóṣúà 14

Jóṣúà 14:9-15