Jóṣúà 14:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síbẹ̀ èmi ní agbára lónìí, bí ìgbà tí Mósè rán mi jáde. Èmi sì ní agbára láti jáde fún ogun nísinsìnyí gẹ́gẹ́ bí mo ti wà ní ígbà náà.

Jóṣúà 14

Jóṣúà 14:10-15