Jóṣúà 13:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ilẹ̀ àwọn ara Gíbálì, àti gbogbo àwọn Lẹ́bánónì dé ìlà-oòrùn, láti Baalì-Gádì ní ìṣàlẹ̀ Okè Hámónì dé Lebo-Hámátì.

Jóṣúà 13

Jóṣúà 13:1-6