Jóṣúà 13:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n fún ẹ̀yà Léfì, Mósè kò fi ogún fún un; Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ní ogún wọn, gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe ìlérí fún wọn.

Jóṣúà 13

Jóṣúà 13:27-33