Jóṣúà 13:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ìdajì Gílíádì, àti Ásítarótù àti Édírérì (àwọn ìlú ọba Ógù ní Básánì). Èyí ni fún irú àwọn ọmọ Mákírì ọmọ Mánásè fún ààbọ̀ àwọn ọmọ Mákírì, ní agbo ilé ní agbo ilé.

Jóṣúà 13

Jóṣúà 13:21-33