Jóṣúà 13:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbègbè ìlú Jásérì, gbogbo ìlú Gílíádì àti ìdajì orílẹ̀ èdè àwọn ọmọ ará Ámónì títí dé Áróérì ní ẹ̀bá Rábà;

Jóṣúà 13

Jóṣúà 13:21-32