Jóṣúà 13:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ààlà àwọn ọmọ Rúbẹ́nì ni etí odò Jọ́dánì. Àwọn ìlú wọ̀nyí àti abúlé rẹ̀ ni ilẹ̀ ìní àwọn ọmọ Rúbẹ́nì ní agbo ilé ní agbo ilé.

Jóṣúà 13

Jóṣúà 13:16-32