Jóṣúà 13:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti Gílíádì, ní agbégbé àwọn ènìyàn Gésúrì àti Máákà, gbogbo Okè Hámónì àti gbogbo Básánì títí dé Sálẹ́kà,

Jóṣúà 13

Jóṣúà 13:5-17