Jóṣúà 10:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóṣúà sì ṣẹ́gun wọn láti Kadeṣi Báníyà sí Gásà àti láti gbogbo agbègbè Góṣénì lọ sí Gíbíónì.

Jóṣúà 10

Jóṣúà 10:38-43