Jóṣúà 10:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ gòkè wá, kí ẹ sì ràn mi lọ́wọ́ láti kọlu Gíbíónì, nítorí tí ó ti wà ní ìrẹ́pọ̀ pẹ́lú Jóṣúà ti àwọn ará Ísírẹ́lì.”

Jóṣúà 10

Jóṣúà 10:1-12